IGBA TI MO RO ISE IYANU RE L’AIYE MI (TOPE ALABI) lyrics
Posted on | October 2, 2014 | 2 Comments
1. Lat’inu oyun titi d’omowo
Gba mo wa l’omowo
Awon ota o pa mi
Mo ra koro dele olodi
awon ti o fe’in w’aiye rara
Baba O s’o mi
Ore re yi o la k’awe
Lati irakoro titi d’omo irinse
O so mi oo
Titi mo fi wa d’agbalagba
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo wa ri pe O ga o pupo
CHORUS
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo ri pe o ga (3x)
Baba
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo ri pe o ga (3x)
Pupo
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo ri pe o ga (3x)
Baba
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo ri pe o ga (3x)
Pupo
2.
Ogun t’eniyan nja l’agba
O po ju ogun igba ewe lo
Tori eni aiye ba nle t’aiye o ri mu
L’ogun to n’sanra n’dojuko
Idi t’aiye fin le ni
O ye aiye
Olorun mi mo o
Oju ogun l’aiye je
F’eni to wa’aiye o wa se rere
Mo wa ronu jinle anu re l’ori aiye mi
Emi ri pe O ga o pupo
CHORUS
Igba ti mo ro anu re l’ori mi
Mo ri pe o ga (3x)
Baba
Igba ti mo ro anu re l’ori mi
Mo ri pe o ga (3x)
pupo
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo ri pe o ga (3x)
Baba
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo ri pe o ga (3x)
Pupo
3.
Ose Olorun Iwo lo je k’ewu aiye fo mi da
Iya to je mi, o je k’o je mi gbe o BABA Oseun
Sebi Iwo ni, apomo ma wehin
Olusegun fun ni, Olorun Iwo ni
Iwo lo gbemiro
Eniyan o le seyi o afi Iwo
Ogbemi soke gogoro
Osuba re re o Baba
Eyin mo se isiro fun titi
Ogbon ori mi o gbe
Igba ti mo ro Ife nla re lori mi
Mo ri pe O ga (3x)
Baba
Igba ti mo ro Ife nla re lori mi
Mo ri pe O ga (3x)
Pupo
CHORUS
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo ri pe o ga (3x)
Baba
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo ri pe o ga (3x)
Baba
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo ri pe o ga (3x)
Pupo
Igba ti mo ro Ise Iyanu re l’aiye mi
Mo ri pe o ga (3x)
Pupo
Olorun to ga O wa L’oke
Olorun t’o nbe ninu aiye
O kere titi O gba n’nu eniyan
O wa l’otun wa
O wa l’osi wa
Ayika wa gbogbo o wa nibe
Oun l’Olorun abeti lukara
L’arin alawo dudu o n’sise e lo
Awon eniyan won rise re
Alawo funfun won’teriba fun
Alaimokan won n’se ibere wipe
Ta l’Olorun Ta l’Olorun
Ayanfe e ma da won l’ohun wipe
Ibi gbogbo lo wa (2x)
Olorun Agbaiye
Ibi gbogbo lo wa (2x)
Ani ko sibi t’oju Olorun ko to
Ibi gbogbo lo wa
Olorun nla apejuba araiye lorun
Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo l’Olorun n’gbe o
Ibi gbogbo lo wa
O nbe l’aiye emi woli toto ni
Ibi gbogbo lo wa
Oro Gbe nu omo eniyan f’ohun
Ibi gbogbo lo wa
Oti saju aiye de, O mo inu aiye, agbehin aiye
Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo lo wa Oledumare
Ibi gbogbo lo wa
O n’be l’arin awon angeli mimo
Ibi gbogbo lo wa
Ko s’ibi ti e pe Olorun si, ti ko wa o
Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo lo wa Baba o
Ibi gbogbo lo wa
Olorun Ajanaku
Ibi gbogbo lo wa
O n’be l’okan re to ba gba laye
Ibi gbogbo lo wa
Ibi gbogbo lo wa
(C) TOPE ALABI
Comments
2 Responses to “IGBA TI MO RO ISE IYANU RE L’AIYE MI (TOPE ALABI) lyrics”
Leave a Reply
August 11th, 2016 @ 9:20 am
what a praise
July 15th, 2017 @ 1:52 pm
Am being touched,amazing praise