MA F’owo mi yin o l’ogo
Ma f’oun ti mo ni yin o Baba
Ere kini mo le je fun o
Nigbati mo ba ti wo nu ile lo
Erupe ile ko le yin o logo o
Baba Mimo
MA F’owo mi yin o l’ogo
Ma f’oun ti mo ni yin o Baba
Ere kini mo le je fun o
Nigbati mo ba ti wo nu ile lo
Erupe ile ko le yin o logo o
Baba Mimo