B’omokunri ti nwo oju Baba re
Posted on | July 2, 2013 | No Comments
B’omokunri ti nwo oju baba re
B’omobirin ti now oju iya re
L’emi o wo Jesu
L’emi o wo Jesu
Titi o fi da mi lola
Mo woju re
Olorun mi
Mo woju re
Eleda mi
B’omokunri ti nwo oju baba re
L’emi o wo Jesu
Titi o fi da mi lola
Category: YORUBA
Comments
Leave a Reply