Ijoba Orun lere onigbagbo o
Ijoba Orun lere onigbagbo o
Ma jen kuna Baba
Mumi dele o
Ma jen kuna Baba se
Mumi dele o
Owo ti mo ni Ko le mumi dele o
Moto ti mo ra ko le wa mi dele o
Ore ti mo ni Ko le sin mi dele o
Gbogbo iwe ti mo ri ka, ko le gbe mi dele o
Ma jen kuna Baba
Mumi dele o
Ki ma ku sajo bi efin
Mumi dele o
Mumi dele o
Aiye l oja orun ni ile
Mumi dele o
Aiye l oja orun ni ile se
Mumi dele o
Mu mi dele o (8x)
Ma jen kuna Baba oooo Baba oooo
Mumi dele o
Mu mi dele o (5)
Ile ayo (2)
Ile Alafia
Ile ogo
Ijoba Orun lere onigbagbo o
Ijoba Orun lere onigbagbo o
Ma Jen Kuna