MO L’OLUWA TO TO GBOJULE Praise 11 years ago Mo l’Oluwa t’o to gbojule Mo l’Olugbala to l’agbara Aiye, Ese, esu ko le gba mi lowo re Baba mo SIMI le O