IWO NI MO NI L’AIYE L’ORUN
Posted on | June 27, 2013 | 2 Comments
IWO ni mo ni l’aiye l’orun
IWO ni mo ni
Jesu IWO ni mo ni
Jesu IWO ni no mi
All I have is you in heaven and earth
All I have is you
Jesus all I have is you
Jesus all I have is you
Category: YORUBA
Comments
2 Responses to “IWO NI MO NI L’AIYE L’ORUN”
Leave a Reply
September 25th, 2018 @ 1:39 pm
Nice song.
I have been trying to watch the video on youtube but i could not find it. Who sang the song please?
February 14th, 2019 @ 1:23 pm
*IWO ni mo ni*
Intro:
Iwooooooo ni ooooooo
Asoro ma ta se
Iwooooooo ni ooooooo
Oba to laye
Iwooooooo ni ooooooo
Iwo ni mo ni
laye lorun o
Iwo ni
Jesu, iwo ni mo ni
Jesu, iwo ni mo ni
Solo 1:
Oba to laye – Iwo ni o
Asoro ma ta se – Iwo ni o
Oba to laye – Iwo ni o
Iwo ni mo ni
Laye Lorun o
Iwo ni
Jesu, iwo ni mo ni
Jesus, iwo ni mo ni
ALL:
1. (IWO ni mo ni o)
IWO ni mo ni – l’aiye l’orun
IWO ni mo ni (2x)
Jesu IWO ni mo ni
Jesu IWO ni mo ni
2. (Iwo ni mo gbojule)
Iwo ni mo gbojule l’aiye l’orun
Iwo ni mo gbojule (2x)
Jesu IWO ni mo ni
Jesu IWO ni mo ni
3. (Iwo lokan mi fe o)
Iwo lokan mi fe l’aiye l’orun
Iwo lokan mi fe (2x)
Jesu Iwo lokan mi fe
Jesu Iwo lokan mi fe
Solo 2:
Oba to laye – Iwo ni o
Asoro ma ta se – Iwo ni o
Oba to laye – Iwo ni o
Iwo ni mo ni
Laye Lorun o
Iwo ni
Jesu, iwo ni mo ni
Jesu, iwo ni mo ni
All: (All I have is you)
All I have is you in heaven and earth
All I have is you (2x)
Jesus all I have is you
Jesus all I have is you