Oluwa ti s’oun nla
T’enikankan K’o le se
Eniyan l’o ti pari
Sugbon Baba ti se o
Nitori na mo yin O
O se baba
Ose Baba Ose Omo(2x)
Agbanilagbatan o! Ose Baba (2x)
Bi Ko ba si re
Nibo ni nba wa o
Bi Ko ba si re
Iru aiye wo ni nba gbe
Agbanilagbatan o
O se Baba